Lara George - Ijoba orun (With Lyrics)
Uhhhuhhhh
Uhuh
Ijoba orun
Ere Onigbagbo o
Ijoba orun
Ere Onigbagbo o
Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ma je n kuna
Baba se
Mu mi dele o
Owo ti mo ni
ko le mu mi dele o
Moto ti mo ri ra
ko le wa mi dele o
Ore ti mo ni
ko le sinmi dele o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
won o le gbe mi dele o
Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
ki n ma ku sajo bi efin
Mu mi dele o
Aye loja, oorun ni ile
Mu mi dele o
Aye loja yi, oorun nile se
Mu mi dele o
Mu mi dele o (x8)
Ma ma je n kuna
Baba ooo
Baba ooo
Mu mi dele o (x5)
Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia
Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia
Ijoba orun
Ere onigbagbo o
Ijoba oorun
Ere onigbagbo o
Ma je n kuna
Link:
*You can copy and share with all your friends
Nigerian Music
Embed Code:
Posted On: Wed, 30 Nov -001 00:00:00 +0013 | Problems?: [email protected]
Body
|
Rating:
3.5/5 average , 63 ratings
Drop your comment
Register or login to write a comment Title:Body
Comments on this music
People who like this music (153)
Playlist (Autoplaying)
Nwa Baby Remix feauturing (Reaction by Ladonsyl) (Champion by Pype)
by Ladonsyl, Flavor, General Pype
by Ladonsyl, Flavor, General Pype
Related
Top Songs
GODSPOWERPROJECT Presents: YAF Area59 in Word Explorers Forum- April Edition
by Youth Alive Fellowship Area59 ft Pastor Obatomi
by Youth Alive Fellowship Area59 ft Pastor Obatomi