9JA DJ Lukas ft Sexy Wizzy - PRAYER (With Lyrics)

Prayer by DJ Lukas ft Sexywizzy
The lyrics:- Mercies of the lord come down unto your children oh iyeme ooo!!!
Motún ti dóde kére SexyWizzy re oo DJ Lukas
Kórí dákun kó gbé mi kore
Kèlèdá mi jò malo sùn le
Kómá ba lò di gòbe
As I dey hustle nígbàwo ni maga go pay
Moti hustle lábúlé
Ará nkan mí moti hustle gidi gan
I don hustle so tey
When I dey cry for my room nobody to say it’s okay
Won dè só pèlé ehn ehn 2x
Won so pótó ayé mà le o 2x
Kí Olúwa má gbagbe mi
Kí èmí òrun ba le mi
Ki Àdàbà mímó látòrun kó bà lé èjìká mi
Kí Olúwa má gbagbé mi
Kí èmí òrun ba lé mi
Èmi gan fé bínú tán mo fe lo jayé Miami.
My father my God o
I dey pray everyday say make I rise say make I no fall o
Òkè leye ñ fò lókè ni mo fé ma lo o
Oba tó n gbó ekún àdúrà èlíjàh
Jòwó gbó àdúrà mi o
Èmi gan fé lo mótò àwon kan ò ló rí méjì
Ki nlo car park kiní mofé Lamborghini meji
Milli milli ni mofe ma ná i won pop Rosè
Mofé ma gbó SexyWizzy ni everywhere lotun lósì
Me I won to chop up I no won wear dunlop
Te te se òjò nlo,òjò n gorí òjò
Me I won to chop up I no won wear dunlop
Te te se òjò nlo,òjò n gorí òjò
Kí Olúwa má gbà gbé mi
Kí èmí òrun kí ó bà lé mi
Àdàbà mímó láti orun kí ó bà lèjìká mi
Kí Olúwa má gbàgbé mi
Kí èmí òrun ko ba le mi
Èmi gan fé bínú tán mo fe lo jayé miami
My father my God o
I dey pray everyday say make I rise say make I no fall o
Òkè leye ñ fò lókè ni mo fé ma lo o
Oba tó n gbó ekún àdúrà èlíjàh
Jòwó gbó àdúrà mi o DJ Lukas
Moti hustle lábúlé
Ará nkan mí moti hustle gidi gan
I don hustle so tay
When I dey cry for my room nobody to say it’s okay
Won dè so pèlé ehn ehn 2x
Won so pótó ayé mà le o 2x
Kí Olúwa má gbàgbé mi
Kí èmí òrun bà lé mi
Àdàbà mímó látòrun ko bà lé èjìká mi
Kí Olúwa má gbàgbé mi
Kí èmí òrun bà lé mi
Èmi gan fé bínú tán mo fe lo jayé Miami
My father my God o
I dey pray everyday say make I rise say make I no fall o
Òkè leye ñ fò lókè ni mo fé ma lò o
Oba tó n gbó ekún àdúrà èlíjàh
Jòwó gbó àdúrà mi o
Kí Olúwa má gbà gbé mi
Kí èmí òrun kí ó bà lé mi
KÀdàbà mímó yeeeh eh
Motún ti dóde kére SexyWizzy reee DJ Luukaas Dj Lukas o.
Drop your comment
Register or login to write a comment Title:Body