AWON OMOGE ODE ONI TIMAA N PARO JU!
Share on NP
Kilo faa ti awon omoge wonyi fimaa n paro bayii?..won awa si Naijapals won a maa so nkan ti won o mon,, nkan to n dunmi ni wipe opolopo awon olodo okunrin naa atun ma bawon fowosowopo...o yeka le gbogbo won kuro ni saiti yii ni!